caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Muminoon, ẹsẹ 56

Mecca · revelation order 74 · 23:56

نُسَارِعُ لَهُمْ فِى ٱلْخَيْرَٰتِ بَل لَّا يَشْعُرُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelni A óò ṣe máa yára ti àwọn oore sí ọ̀dọ̀ wọn lọ (títí láéláé). Rárá, wọn kò fura ni![1]
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70