caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Taa-Haa, ẹsẹ 102

Mecca · revelation order 45 · 20:102

يَوْمَ يُنفَخُ فِى ٱلصُّورِ وَنَحْشُرُ ٱلْمُجْرِمِينَ يَوْمَئِذٍ زُرْقًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNí ọjọ́ tí wọ́n á fọn fèrè oníwo fún àjíǹde. A sí máa kó àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ jọ ní ọjọ́ yẹn, tí ojú wọn yó sì dúdú batakun.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70