caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Baqara, ẹsẹ 18

Medina · revelation order 87 · 2:18

صُمٌّۢ بُكْمٌ عُمْىٌ فَهُمْ لَا يَرْجِعُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelAdití, ayaya, afọ́jú ni wọ́n; nítorí náà wọn kò níí ṣẹ́rí padà.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70