caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Maryam, ẹsẹ 65

Mecca · revelation order 44 · 19:65

رَّبُّ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلْأَرْضِ وَمَا بَيْنَهُمَا فَٱعْبُدْهُ وَٱصْطَبِرْ لِعِبَٰدَتِهِۦ هَلْ تَعْلَمُ لَهُۥ سَمِيًّا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelOlúwa àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ àti ohun tí ń bẹ láààrin àwọn méjèèjì. Nítorí náà, jọ́sìn fún Un, kí ó sì ṣe sùúrù lórí ìjọ́sìn Rẹ̀. Ǹjẹ́ o mọ ẹni tí ó tún ń jẹ́ orúkọ Rẹ̀?
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70