caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Israa, ẹsẹ 53

Mecca · revelation order 50 · 17:53

وَقُل لِّعِبَادِى يَقُولُوا۟ ٱلَّتِى هِىَ أَحْسَنُ إِنَّ ٱلشَّيْطَٰنَ يَنزَغُ بَيْنَهُمْ إِنَّ ٱلشَّيْطَٰنَ كَانَ لِلْإِنسَٰنِ عَدُوًّا مُّبِينًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelSọ fún àwọn ẹrúsìn Mi pé kí wọ́n máa sọ èyí tó dára jùlọ (nínú ọ̀rọ̀). Dájúdájú aṣ-Ṣaetọ̄n yóò máa dá yánpọn-yánrin sílẹ̀ láààrin wọn. Dájúdájú aṣ-Ṣaetọ̄n jẹ́ ọ̀tá pọ́nńbélé fún ènìyàn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70