فَأَخَذَتْهُمُ ٱلصَّيْحَةُ مُشْرِقِينَ Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, ohùn igbe mú wọn nígbà tí òòrùn òwúrọ̀ yọ sí wọn.