caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ar-Ra'd, ẹsẹ 19

Medina · revelation order 96 · 13:19

أَفَمَن يَعْلَمُ أَنَّمَآ أُنزِلَ إِلَيْكَ مِن رَّبِّكَ ٱلْحَقُّ كَمَنْ هُوَ أَعْمَىٰٓ إِنَّمَا يَتَذَكَّرُ أُو۟لُوا۟ ٱلْأَلْبَٰبِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelǸjẹ́ ẹni tí ó mọ̀ pé òdodo kúkú ni n̄ǹkan tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ fún ọ láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ, ó wa dà bí ẹni tí ó fọ́jú (nípa rẹ̀ bí)? Àwọn onílàákàyè ló ń lo ìrántí.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70