caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ash-Shams, ẹsẹ 13

Mecca · revelation order 26 · 91:13

فَقَالَ لَهُمْ رَسُولُ ٱللَّهِ نَاقَةَ ٱللَّهِ وَسُقْيَٰهَا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNígbà náà, Òjíṣẹ́ Allāhu sọ fún wọn pé: “(Ẹ fi) abo ràkúnmí Allāhu àti omi rẹ̀ (sílẹ̀).”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70