caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ash-Shams, ẹsẹ 12

Mecca · revelation order 26 · 91:12

إِذِ ٱنۢبَعَثَ أَشْقَىٰهَا

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Rántí) nígbà tí ẹni tí orí rẹ̀ burú jùlọ nínú wọn sáré dìde (láti gún ràkúnmí pa).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70