caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Inshiqaaq, ẹsẹ 25

Mecca · revelation order 83 · 84:25

إِلَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُوا۟ وَعَمِلُوا۟ ٱلصَّٰلِحَٰتِ لَهُمْ أَجْرٌ غَيْرُ مَمْنُونٍۭ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀyàfi àwọn tó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe àwọn iṣẹ́ rere, ẹ̀san tí kò níí pin[1] ń bẹ fún wọn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70