وَإِذَا ٱلْجِبَالُ سُيِّرَتْ Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàti nígbà tí wọ́n bá mú àwọn àpáta rìn (kúrò ní àyè wọn, tí wọ́n kù wọ́n dànù),