caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Qalam, ẹsẹ 43

Mecca · revelation order 2 · 68:43

خَٰشِعَةً أَبْصَٰرُهُمْ تَرْهَقُهُمْ ذِلَّةٌ وَقَدْ كَانُوا۟ يُدْعَوْنَ إِلَى ٱلسُّجُودِ وَهُمْ سَٰلِمُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelOjú wọn yóò wálẹ̀. Ìyẹpẹrẹ máa bò wọ́n mọ́lẹ̀. Wọ́n kúkú ti pè wọ́n síbi ìforíkanlẹ̀ nígbà tí wọ́n ní àlàáfíà (wọn kò sì kírun).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70