caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Qalam, ẹsẹ 34

Mecca · revelation order 2 · 68:34

إِنَّ لِلْمُتَّقِينَ عِندَ رَبِّهِمْ جَنَّٰتِ ٱلنَّعِيمِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra wà fún àwọn olùbẹ̀rù Allāhu lọ́dọ̀ Olúwa wọn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70