caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Jumu'a, ẹsẹ 7

Medina · revelation order 110 · 62:7

وَلَا يَتَمَنَّوْنَهُۥٓ أَبَدًۢا بِمَا قَدَّمَتْ أَيْدِيهِمْ وَٱللَّهُ عَلِيمٌۢ بِٱلظَّٰلِمِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelWọn kò níí tọrọ rẹ̀ láéláé nítorí ohun tí ọwọ́ wọn ti tì ṣíwájú. Allāhu sì ni Onímọ̀ nípa àwọn alábòsí.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70