caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà At-Tur, ẹsẹ 48

Mecca · revelation order 76 · 52:48

وَٱصْبِرْ لِحُكْمِ رَبِّكَ فَإِنَّكَ بِأَعْيُنِنَا وَسَبِّحْ بِحَمْدِ رَبِّكَ حِينَ تَقُومُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelṢe sùúrù fún ìdájọ́ Olúwa Rẹ, dájúdájú ìwọ wà ní ojútó Wa. Kí ó sì ṣe àfọ̀mọ́ pẹ̀lú ẹyìn fún Olúwa rẹ nígbà tí o bá fẹ́ dìde.[1]
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70