caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Qaaf, ẹsẹ 36

Mecca · revelation order 34 · 50:36

وَكَمْ أَهْلَكْنَا قَبْلَهُم مِّن قَرْنٍ هُمْ أَشَدُّ مِنْهُم بَطْشًا فَنَقَّبُوا۟ فِى ٱلْبِلَٰدِ هَلْ مِن مَّحِيصٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelMélòó mélòó nínú àwọn ìjọ tí A ti parẹ́ ṣíwájú wọn. Wọ́n sì ní agbára jù wọ́n lọ. (Nígbà tí ìyà dé) wọ́n sá àsálà kiri nínú ìlú. Ǹjẹ́ ibùsásí kan wà (fún wọn bí?)
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70