إِنَّ ٱلَّذِينَ يُنَادُونَكَ مِن وَرَآءِ ٱلْحُجُرَٰتِ أَكْثَرُهُمْ لَا يَعْقِلُونَ
Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú àwọn tó ń pè ọ́ láti ẹ̀yìn àwọn yàrá[1], ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò ṣe làákàyè.
إِنَّ ٱلَّذِينَ يُنَادُونَكَ مِن وَرَآءِ ٱلْحُجُرَٰتِ أَكْثَرُهُمْ لَا يَعْقِلُونَ