caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ad-Dukhaan, ẹsẹ 40

Mecca · revelation order 64 · 44:40

إِنَّ يَوْمَ ٱلْفَصْلِ مِيقَٰتُهُمْ أَجْمَعِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú ọjọ́ òpínyà (ìyẹn, ọjọ́ àjíǹde) ni àkókò àdéhùn fún gbogbo wọn pátápátá.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70