وَءَاتَيْنَٰهُم مِّنَ ٱلْـَٔايَٰتِ مَا فِيهِ بَلَٰٓؤٌا۟ مُّبِينٌ Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelA sì fún wọn ní àwọn àmì tí àdánwò pọ́nńbélé wà nínú rẹ̀.