caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Fussilat, ẹsẹ 38

Mecca · revelation order 61 · 41:38

فَإِنِ ٱسْتَكْبَرُوا۟ فَٱلَّذِينَ عِندَ رَبِّكَ يُسَبِّحُونَ لَهُۥ بِٱلَّيْلِ وَٱلنَّهَارِ وَهُمْ لَا يَسْـَٔمُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelTí wọ́n bá sì ṣègbéraga, àwọn tó wà ní ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ, wọ́n ń ṣàfọ̀mọ́ fún Un ní alẹ́ àti ní ọ̀sán; wọn kò sì kágara.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70