caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà As-Saaffaat, ẹsẹ 19

Mecca · revelation order 56 · 37:19

فَإِنَّمَا هِىَ زَجْرَةٌ وَٰحِدَةٌ فَإِذَا هُمْ يَنظُرُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, igbe ẹyọ kan mà ni. Nígbà náà ni wọn yóò máa wò sùn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70