caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà As-Saaffaat, ẹsẹ 177

Mecca · revelation order 56 · 37:177

فَإِذَا نَزَلَ بِسَاحَتِهِمْ فَسَآءَ صَبَاحُ ٱلْمُنذَرِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNígbà tí ó bá sọ̀kalẹ̀ sí gbàgede wọn, òwúrọ̀ ọjọ́ náà yó sì burú fún àwọn ẹni-akìlọ̀-fún.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70