caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà As-Saaffaat, ẹsẹ 105

Mecca · revelation order 56 · 37:105

قَدْ صَدَّقْتَ ٱلرُّءْيَآ إِنَّا كَذَٰلِكَ نَجْزِى ٱلْمُحْسِنِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelo kúkú ti mú àlá náà ṣẹ. Dájúdájú báyẹn ni Àwa ṣe ń san àwọn olùṣe-rere ní ẹ̀san (rere).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70