caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Yaseen, ẹsẹ 12

Mecca · revelation order 41 · 36:12

إِنَّا نَحْنُ نُحْىِ ٱلْمَوْتَىٰ وَنَكْتُبُ مَا قَدَّمُوا۟ وَءَاثَٰرَهُمْ وَكُلَّ شَىْءٍ أَحْصَيْنَٰهُ فِىٓ إِمَامٍ مُّبِينٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú Àwa l’À ń sọ àwọn òkú di alàyè. A sì ń ṣe àkọsílẹ̀ ohun tí wọ́n tì síwájú àti orípa (iṣẹ́ ọwọ́) wọn. Gbogbo n̄ǹkan ni A ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ sínú tírà kan tó yanjú.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70