caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Qasas, ẹsẹ 51

Mecca · revelation order 49 · 28:51

وَلَقَدْ وَصَّلْنَا لَهُمُ ٱلْقَوْلَ لَعَلَّهُمْ يَتَذَكَّرُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀti pé dájúdájú A ti ṣe àlàyé ọ̀rọ̀ náà fún wọn nítorí kí wọ́n lè lo ìrántí.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70