ثُمَّ أَغْرَقْنَا بَعْدُ ٱلْبَاقِينَ Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelLẹ́yìn náà, A tẹ àwọn tó ṣẹ́kù lẹ́yìn wọn rì sínú omi.