caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Furqaan, ẹsẹ 73

Mecca · revelation order 42 · 25:73

وَٱلَّذِينَ إِذَا ذُكِّرُوا۟ بِـَٔايَٰتِ رَبِّهِمْ لَمْ يَخِرُّوا۟ عَلَيْهَا صُمًّا وَعُمْيَانًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Àwọn ni) àwọn tí ó jẹ́ pé tí wọ́n bá fi àwọn āyah Olúwa wọn ṣèrántí fún wọn, wọn kò dà lulẹ̀ bí adití àti afọ́jú.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70