caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Furqaan, ẹsẹ 62

Mecca · revelation order 42 · 25:62

وَهُوَ ٱلَّذِى جَعَلَ ٱلَّيْلَ وَٱلنَّهَارَ خِلْفَةً لِّمَنْ أَرَادَ أَن يَذَّكَّرَ أَوْ أَرَادَ شُكُورًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÒun ni Ẹni tí Ó ṣe òru àti ọ̀sán ní ìtẹ̀léǹtẹ̀lé (tí ìkíní yàtọ̀ sí ìkejì) nítorí ẹni tí ó bá gbèrò láti ṣe ìrántí (Allāhu) tàbí tí ó bá gbèrò ìdúpẹ́ (fún Un).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70