caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Furqaan, ẹsẹ 12

Mecca · revelation order 42 · 25:12

إِذَا رَأَتْهُم مِّن مَّكَانٍۭ بَعِيدٍ سَمِعُوا۟ لَهَا تَغَيُّظًا وَزَفِيرًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNígbà tí (Iná náà) bá rí wọn láti àyè kan tí ó jìnnà, wọn yó sì máa gbọ́ ohùn ìbínú àti kíkùn (rẹ̀).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70