caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Muminoon, ẹsẹ 48

Mecca · revelation order 74 · 23:48

فَكَذَّبُوهُمَا فَكَانُوا۟ مِنَ ٱلْمُهْلَكِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, wọ́n pe àwọn méjèèjì ní òpùrọ́. Wọ́n sì wà nínú àwọn olùparun.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70