caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Taa-Haa, ẹsẹ 115

Mecca · revelation order 45 · 20:115

وَلَقَدْ عَهِدْنَآ إِلَىٰٓ ءَادَمَ مِن قَبْلُ فَنَسِىَ وَلَمْ نَجِدْ لَهُۥ عَزْمًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú A ṣe àdéhùn fún (Ànábì) Ādam ṣíwájú. Ṣùgbọ́n ó gbàgbé. A kò sì bá a pẹ̀lú ìpinnu ọkàn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70