caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Maryam, ẹsẹ 81

Mecca · revelation order 44 · 19:81

وَٱتَّخَذُوا۟ مِن دُونِ ٱللَّهِ ءَالِهَةً لِّيَكُونُوا۟ لَهُمْ عِزًّا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelWọ́n sọ àwọn kan di ọlọ́hun lẹ́yìn Allāhu nítorí kí wọ́n lè fún wọn ní agbára.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70