caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Kahf, ẹsẹ 80

Mecca · revelation order 69 · 18:80

وَأَمَّا ٱلْغُلَٰمُ فَكَانَ أَبَوَاهُ مُؤْمِنَيْنِ فَخَشِينَآ أَن يُرْهِقَهُمَا طُغْيَٰنًا وَكُفْرًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNí ti ọmọdékùnrin náà, àwọn òbí rẹ̀ méjèèjì jẹ́ onígbàgbọ́ òdodo. A sì ń bẹ̀rù pé kí ó màa kó ìtayọ ẹnu-ààlà àti àìgbàgbọ́ bá àwọn méjèèjì.[1]
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70