caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Kahf, ẹsẹ 103

Mecca · revelation order 69 · 18:103

قُلْ هَلْ نُنَبِّئُكُم بِٱلْأَخْسَرِينَ أَعْمَٰلًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelSọ pé: “Ṣé kí Á fún yín ní ìró àwọn ẹni òfò jùlọ nípa iṣẹ́ (ọwọ́ wọn)?
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70