caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-A'raaf, ẹsẹ 120

Mecca · revelation order 39 · 7:120

وَأُلْقِىَ ٱلسَّحَرَةُ سَٰجِدِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelIṣẹ́ ìyanu (Ànábì Mūsā) mú àwọn òpìdán wó lulẹ̀, tí wọ́n forí kanlẹ̀ (fún Allāhu).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70