caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà At-Taghaabun, ẹsẹ 3

Medina · revelation order 108 · 64:3

خَلَقَ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلْأَرْضَ بِٱلْحَقِّ وَصَوَّرَكُمْ فَأَحْسَنَ صُوَرَكُمْ وَإِلَيْهِ ٱلْمَصِيرُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÓ ṣẹ̀dá àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ pẹ̀lú òdodo. Ó ya àwòrán yín. Ó sì ṣe àwọn àwòrán yín dáradára. Ọ̀dọ̀ Rẹ̀ sì ni àbọ̀ ẹ̀dá.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70