caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Munaafiqoon, ẹsẹ 5

Medina · revelation order 104 · 63:5

وَإِذَا قِيلَ لَهُمْ تَعَالَوْا۟ يَسْتَغْفِرْ لَكُمْ رَسُولُ ٱللَّهِ لَوَّوْا۟ رُءُوسَهُمْ وَرَأَيْتَهُمْ يَصُدُّونَ وَهُم مُّسْتَكْبِرُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀti pé nígbà tí wọ́n bá sọ fún wọn pé: “Ẹ wá kí Òjíṣẹ́ ba yín tọrọ àforíjìn.” Wọ́n á gbúnrí. O sì máa rí wọn tí wọn yóò máa gbúnrí lọ, tí wọn yóò máa ṣègbéraga.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70