caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà As-Saff, ẹsẹ 4

Medina · revelation order 109 · 61:4

إِنَّ ٱللَّهَ يُحِبُّ ٱلَّذِينَ يُقَٰتِلُونَ فِى سَبِيلِهِۦ صَفًّا كَأَنَّهُم بُنْيَٰنٌ مَّرْصُوصٌ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú Allāhu fẹ́ràn àwọn tó ń jagun sí ojú-ọ̀nà Rẹ̀ (tí wọ́n tò ní) ọ̀wọ̀ọ̀wọ́ bí ẹni pé ilé tí wọ́n lẹ̀pọ̀ mọ́ra wọn ni wọ́n
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70