caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà As-Saff, ẹsẹ 13

Medina · revelation order 109 · 61:13

وَأُخْرَىٰ تُحِبُّونَهَا نَصْرٌ مِّنَ ٱللَّهِ وَفَتْحٌ قَرِيبٌ وَبَشِّرِ ٱلْمُؤْمِنِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀti n̄ǹkan mìíràn tí ẹ tún nífẹ̀ẹ́ sí; (ìyẹn) àrànṣe láti ọ̀dọ̀ Allāhu àti ìṣẹ́gun tó súnmọ́. Kí o sì fún àwọn onígbàgbọ́ òdodo ní ìró ìdùnnú.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70