caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Hashr, ẹsẹ 13

Medina · revelation order 101 · 59:13

لَأَنتُمْ أَشَدُّ رَهْبَةً فِى صُدُورِهِم مِّنَ ٱللَّهِ ذَٰلِكَ بِأَنَّهُمْ قَوْمٌ لَّا يَفْقَهُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú ẹ̀yin ni ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ tó lágbára ju Allāhu lọ nínú igbá-àyà wọn. Ìyẹn nítorí pé, dájúdájú àwọn ni ìjọ tí kò gbọ́ àgbọ́yé.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70