caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Hadid, ẹsẹ 15

Medina · revelation order 94 · 57:15

فَٱلْيَوْمَ لَا يُؤْخَذُ مِنكُمْ فِدْيَةٌ وَلَا مِنَ ٱلَّذِينَ كَفَرُوا۟ مَأْوَىٰكُمُ ٱلنَّارُ هِىَ مَوْلَىٰكُمْ وَبِئْسَ ٱلْمَصِيرُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, ní òní Àwa kò níí gba ìtánràn kan ní ọwọ́ ẹ̀yin àti àwọn tó ṣàì gbàgbọ́. Iná ni ibùgbé yín. Òhun l’ó tọ́ si yín. Ìkángun náà sì burú.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70