caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ar-Rahmaan, ẹsẹ 33

Medina · revelation order 97 · 55:33

يَٰمَعْشَرَ ٱلْجِنِّ وَٱلْإِنسِ إِنِ ٱسْتَطَعْتُمْ أَن تَنفُذُوا۟ مِنْ أَقْطَارِ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلْأَرْضِ فَٱنفُذُوا۟ لَا تَنفُذُونَ إِلَّا بِسُلْطَٰنٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelẸ̀yin àwùjọ àlùjànnú àti ènìyàn, tí ẹ bá lágbára láti sá jáde nínú àwọn agbègbè sánmọ̀ àti ilẹ̀, ẹ sá jáde. Ẹ kò lè sá jáde àfi pẹ̀lú agbára.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70