caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà At-Tur, ẹsẹ 18

Mecca · revelation order 76 · 52:18

فَٰكِهِينَ بِمَآ ءَاتَىٰهُمْ رَبُّهُمْ وَوَقَىٰهُمْ رَبُّهُمْ عَذَابَ ٱلْجَحِيمِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelWọn yóò máa jẹ ìgbádùn pẹ̀lú ohun tí Olúwa wọn fún wọn. Àti pé (Allāhu) yóò ṣọ́ wọn kúrò níbi ìyà iná Jẹhīm.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70