caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Qaaf, ẹsẹ 1

Mecca · revelation order 34 · 50:1

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ قٓ وَٱلْقُرْءَانِ ٱلْمَجِيدِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelƘọ̄f. (Allāhu ló mọ ohun tí Ó gbàlérò pẹ̀lú àwọn háràfí náà.)[1] (Allāhu fi) al-Ƙur’ān alápọ̀n-ọ́nlé búra.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70