caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ash-Shura, ẹsẹ 37

Mecca · revelation order 62 · 42:37

وَٱلَّذِينَ يَجْتَنِبُونَ كَبَٰٓئِرَ ٱلْإِثْمِ وَٱلْفَوَٰحِشَ وَإِذَا مَا غَضِبُوا۟ هُمْ يَغْفِرُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Ohun tí ó wà lọ́dọ̀ Allāhu tún wà fún) àwọn tó ń jìnnà sí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńlá ńlá àti àwọn ìwà ìbàjẹ́, àti (àwọn tó jẹ́ pé) nígbà tí wọ́n bá bínú, wọn yóò ṣàforíjìn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70