caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Saba, ẹsẹ 42

Mecca · revelation order 58 · 34:42

فَٱلْيَوْمَ لَا يَمْلِكُ بَعْضُكُمْ لِبَعْضٍ نَّفْعًا وَلَا ضَرًّا وَنَقُولُ لِلَّذِينَ ظَلَمُوا۟ ذُوقُوا۟ عَذَابَ ٱلنَّارِ ٱلَّتِى كُنتُم بِهَا تُكَذِّبُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, ní òní apá kan yín kò ní ìkápá àǹfààní, kò sì ní ìkápá ìnira fún apá kan. A sì máa sọ fún àwọn tó ṣàbòsí pé: “Ẹ tọ́ ìyà Iná tí ẹ̀ ń pè ní irọ́ wò.”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70