caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà An-Noor, ẹsẹ 13

Medina · revelation order 102 · 24:13

لَّوْلَا جَآءُو عَلَيْهِ بِأَرْبَعَةِ شُهَدَآءَ فَإِذْ لَمْ يَأْتُوا۟ بِٱلشُّهَدَآءِ فَأُو۟لَٰٓئِكَ عِندَ ٱللَّهِ هُمُ ٱلْكَٰذِبُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelKí ni kò jẹ́ kí wọ́n mú ẹlẹ́rìí mẹ́rin wá lórí rẹ̀? Nítorí náà, nígbà tí wọn kò ti mú àwọn ẹlẹ́rìí wá, àwọn wọ̀nyẹn, àwọn ni òpùrọ́ lọ́dọ̀ Allāhu.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70