caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Muminoon, ẹsẹ 26

Mecca · revelation order 74 · 23:26

قَالَ رَبِّ ٱنصُرْنِى بِمَا كَذَّبُونِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Ànábì) Nūh sọ pé: “Olúwa mi, ṣàrànṣe fún mi nítorí pé wọ́n pè mí ní òpùrọ́.”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70