caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Taa-Haa, ẹsẹ 89

Mecca · revelation order 45 · 20:89

أَفَلَا يَرَوْنَ أَلَّا يَرْجِعُ إِلَيْهِمْ قَوْلًا وَلَا يَمْلِكُ لَهُمْ ضَرًّا وَلَا نَفْعًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelṢé wọn kò rí i pé kò lè dá èsì ọ̀rọ̀ kan padà fún wọn ni, kò sì ní agbára láti kó ìnira tàbí àǹfààní kan bá wọn!
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70