caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Baqara, ẹsẹ 78

Medina · revelation order 87 · 2:78

وَمِنْهُمْ أُمِّيُّونَ لَا يَعْلَمُونَ ٱلْكِتَٰبَ إِلَّآ أَمَانِىَّ وَإِنْ هُمْ إِلَّا يَظُنُّونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀti pé ó wà nínú wọn, àwọn aláìmọ̀ọ́nkọmọ̀ọ́nkà, tí wọn kò nímọ̀ nípa Tírà àfi àwọn irọ́. Wọn kò jẹ́ n̄ǹkan kan bí kò ṣe pé wọ́n ń dá àbá (àròsọ).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70